Oja, is a brand new music with lyrics released in the year 9 September 2019 by a Nigerian singer and songwriter, Mohbad featuring OlaDips. And this amazing audio mp3 is available for download.
After successful making waves with Ghanaian trending social media sensation, Shatta Bandle on his previous heard track, “See My Bounzer,” Bankz Nation Entertainment act, Mohbad wastes no time unleashing another catchy single called “Oja.”
The afrobeat record got assisted by Nigerian rapper, Oladips.
Listen up below!.
DOWNLOAD
LYRICS
Omiata
Oyinbo ẹ ni pepper water
(Ọjà-ọjà-ọjà)
Mohbad, Olorun o bad
(Ọjà-ọjà-ọjà)
Ọmọ iya ajẹ’, ahn ahn (ìmọ’lẹ’)
Ẹyin ọmọ oloja yii
Edakun ẹ rọra ma gboja yii
Eyin omo onyieze onyieze
Mo be yín ‘tori Chineke Chineke, ah
Ẹyin ọmọ oloja yii
Edakun ẹ rọra ma gboja yii
Eyin omo onyieze onyieze
Mo be yín ‘tori Chineke Chineke, ah
Ọjà ọjà ọjà (ọjà dakun májẹ mi)
Ọjà ọjà ọjà (Ọmọ ase to wa lẹgbẹ mi ni ko jẹ’)
Ọjà ọjà ọjà (mi ò fẹ ma pe destiny boy in sir mọ)
Ọjà ọjà ọjà (gbẹnu dá kẹ)
Wòó, ọlọja ni mí, ọlọja ni ẹ
But bimo ṣe n j’ọja ko niwo ṣe njẹ
Kọ’kọ’ mogbo yi ko to claim marlians
Malo fara we wá, awa ti giran tipẹ
Ṣe wọn o sọ fún ẹ ni koto we jombo
Owa de party, o lọ ń jo bi Poco
Pẹ’lẹ’ èèyàn Seun Pizzle, set àwọn Ramon Jago
Ẹ wò ó, oti sun oti gb’ọja
O mu cocoa bi bottle water
Bo ṣe n gbe Ref ma lo ṣe n fa loud
E so fun padi yin ko ma sare wọja
Ẹyin ọmọ oloja yii
Edakun ẹ rọra ma gboja yii
Eyin omo onyieze onyieze
Mo be yín ‘tori Chineke Chineke, ah
Ẹyin ọmọ oloja yii
Edakun ẹ rọra ma gboja yii
Eyin omo onyieze onyieze
Mo be yín ‘tori Chineke Chineke, ah
Ọjà ọjà ọjà (ọjà dakun májẹ mi)
Ọjà ọjà ọjà (Ọmọ ase to wa lẹgbẹ mi ni ko jẹ’)
Ọjà ọjà ọjà (mi ò fẹ ma pe destiny boy in sir mọ)
Ọjà ọjà ọjà (gbẹnu dá kẹ)
Ahn ahn
Oti o n payan, wo igo loti mapa
But Chinozo ti n jọ Chinaza
Ọlọ’run ṣàánú mi má jẹ k’ọja jẹ mi
Jẹ kin délé pe, wo gutter o yẹ mi
Padi f’ọpọlọ si
Má gbagbe ibi to tun fi kọkọrọ si
Nn’kan to balemu ni ko koko ṣi
Malo bawon k’alleluyah ni mosalasi
Won ba e so nisi
On form James Bond
Iya e banger o kin she bomb
Ofe gba penalty, otun ti toe bo
Ita lọ má ti ko omode tio gbon (omo ase)
Ẹyin ọmọ oloja yii
Edakun ẹ rọra ma gboja yii
Eyin omo onyieze onyieze
Mo be yín ‘tori Chineke Chineke, ah
Ẹyin ọmọ oloja yii
Edakun ẹ rọra ma gboja yii
Eyin omo onyieze onyieze
Mo be yín ‘tori Chineke Chineke, ah
Ọjà ọjà ọjà (ọjà dakun májẹ mi)
Ọjà ọjà ọjà (Ọmọ ase to wa lẹgbẹ mi ni ko jẹ’)
Ọjà ọjà ọjà (mi ò fẹ ma pe destiny boy in sir mọ)
Ọjà ọjà ọjà (gbẹnu dá kẹ)
Aje on the mix.
Do you find Sheldox useful? Click here to give us five stars rating!